We’ve updated our Terms of Use to reflect our new entity name and address. You can review the changes here.
We’ve updated our Terms of Use. You can review the changes here.

Sa Gbekele (Single)

by Tolu Akande

/

lyrics

'Gbat a b'Oluwa rin
N'nu mole oro re
Ona wa yio ti ni mole to
'Gbata a ba nse 'fe Re
On yio ma ba wa gbe
Ati awon t'o gbeke won le

Ko s'ohun t'o le de
L'oke tabi ni'le
T'o le ko agbara Re l'oju
Iyemeji, eru, ibanuje, ekun
Ko le duro bi a gbekele

Sa gbeke le, Ona miran ko si
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe k'a gbekele

Ko si wahala mo
Tabi ibanuje
O ti san gbogbo gbese' wonyi
Ko si arokan mo, Tabi ifa juro
Sugbon bukun, b'a ba gbeke le

Sa gbeke le, Ona miran ko si
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe k'a gbekele

Ako le f'enu so
Bi 'fe Re ti po to
Titi a o f'ara wa rubo
Anu ti o nfihan
At'ayo t'o nfun ni
Je ti awon ti o gbeke le

Sa gbeke le, Ona miran ko si
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe k'a gbekele

Sa gbeke le, Ona miran ko si
Lati l'ayo n'nu Jesu
Ju pe k'a gbekele

credits

released May 6, 2020
Piano, Vocals, Bass, Percussion: Tolu Akande
Soprano Sax: Abraham Ogunlade
Acoustic & Electric Guitars: Jacob Hamilton
Drums: Caleb Graves
Talking Drum: Uncle Leke Azeez


Producer: Tolu Akande
Executive Producers: Amanda, Asaph & Seraphim Akande

license

all rights reserved

tags

about

Tolu Akande Atlanta, Georgia

BOOKING:
470-326-0916

toluakandemusic@gmail.com

Christ-follower. Proudly Nigerian.

"Let me write the songs of a nation, I care not who writes its laws."

The reason why I do hymns? Because the 7 year-old and the 70 year-old alike will sing them. Additionally, they are sound doctrine and theology placed to anointed melodies that have stood the test of time!
... more

contact / help

Contact Tolu Akande

Streaming and
Download help

Shipping and returns

Redeem code

Report this track or account

If you like Tolu Akande, you may also like: