We’ve updated our Terms of Use to reflect our new entity name and address. You can review the changes here.
We’ve updated our Terms of Use. You can review the changes here.

Orin Adura, Volume 2

by Tolu Akande

/
  • Streaming + Download

    Includes unlimited streaming via the free Bandcamp app, plus high-quality download in MP3, FLAC and more.
    Purchasable with gift card

      $8 USD  or more

     

  • Full Digital Discography

    Get all 16 Tolu Akande releases available on Bandcamp and save 25%.

    Includes unlimited streaming via the free Bandcamp app, plus high-quality downloads of Orin Adura, Volume 3, Orin Awe at'Adura (Medley Single), A Nsoro Ile Bukun Ni (Single), Olorun Agbaye (Single), Sa Gbekele (Single), Ma Toju Mi (Single), Orin Adura, Volume 2, Ọba Awọn Ẹni Mimọ (Single), and 8 more. , and , .

    Purchasable with gift card

      $29.25 USD or more (25% OFF)

     

  • Orin Adura, Volume 2 (Compact Disc)
    Compact Disc (CD) + Digital Album

    Hard copy CD of Tolu Akande's, Orin Adura, Volume 2. Yoruba hymns for hymn lovers!

    Includes unlimited streaming of Orin Adura, Volume 2 via the free Bandcamp app, plus high-quality download in MP3, FLAC and more.

    Sold Out

1.
MIMỌ, Mimọ, Mimọ Olodumare, Ni kutukutu ni'wọ o gbọ orin wa, Mimọ, Mimọ, Mimọ! Oniyọnu julọ, Ologo mẹta lai Olubukun. --- Holy, holy, holy Lord, God Almighty Early in the morning our song shall rise to Thee Holy, holy, holy Merciful and mighty God in three persons blessed Trinity
2.
1. ỌBA awọn ẹni mimọ T'o mọ 'ye awọn 'rawọ; Ọpọ ẹni t'Ẹda gbagbe, Wa yika itẹ Rẹ lai. Egbe: Mimọ Mimọ (6 times) Lo ye Ọ, Iwọ l'a ba ma f'iyin fun, Ọlọrun, Edumare. 2. Ẹni t'o wa ninu 'mọlẹ, T'oju ẹnikan ko ri; Mose ri akẹyinsi Rẹ, Oju Mose ran b'orun. 3. Mole ti ‘kuku aiye bo Ntan mole roro loke Nwon je omo alade l'orun Eda gbagbe won t‘aiye. 4. Lala at'iya wọn fun Ọ, Ẹda ko royin rẹ mọ; Iwa rere wọn farasin, Oluwa nikan lo mọ. Egbe: Mimọ Mimọ (6 times) Lo ye Ọ, Iwọ l'a ba ma f'iyin fun, Ọlọrun, Edumare.
3.
4.
5.
1. JESU lorukọ to ga ju, Layé a ti lọrun; Awọn Angẹli wolẹ fun, Esu, bẹru o sa. Egbe: Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ, Ipe miiran ko si, O daju wi pé Jesu ku, Ani f'emi ẹlẹsẹ. 3. Olugbala sẹgun iku, Ijọba Satan fọ; Gbogbo ẹda ẹ bu sayọ, Ka yin Baba logo. Egbe: Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,.....etc. 7. Jesu, fọ itẹgun esu, Iwọ l'Ọba Ogo; Iyin, ope ni fun Baba, Ni fun Mẹtalọkan. Egbe: Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ, Ipe miran ko si, O daju wi pé Jesu ku, Ani f' emi ẹlẹsẹ.
6.
1. KÉRÚBÙ pẹlu Séráfù, Ki yoo si nkan, B'esu gbe tasi rẹ si wa, Ki yoo si nkan, Maikel Mimọ Balogun wa, Y'o fọ 'tẹgun esu tutu, Esu y'o wolẹ lẹsẹ wa, Ko le si nkan. 2. Asiwaju ẹ ma bẹru Ki yoo si nkan; 'Gbati Jesu wa pẹlu wa, Ki yoo si nkan, Sa gbadura, Asiwaju, Oke nla yoo di pẹtẹlẹ, Ayé ko le ri wa gbe se, Ko le si nkan. 6. Ẹgbẹ Akọrin ẹ mura, Ki yoo si nkan Aluduru at'Afunpe, Ki yoo si nkan; Mura lati kọrin Mose, K'ẹ yin Ọdaguntan logo, K'a jumọ kọ Halleluyah, Ko le si nkan. 8. Ogo ni fun Baba l'oke, Ki yoo si nkan; Ogo ni fun Ọmọ l'oke, Ki yoo si nkan; Ogo ni fun Ẹmi Mimọ , Ogo ni fun Mẹtalọkan, Lagbara Olodumare, Ko le si nkan.
7.
OHUN t'a fi fun Ọ Tirẹ ni Oluwa: Gbogbo ohun ti a si ni, Ọwọ Rẹ lo ti wa. Jẹ k'a gba ẹbun Rẹ, Bi iriju rere; Bi O si ti mbukun wa to, Bẹ l'a o fi fun Ọ. K'a tu onde silẹ, K'a f'ọna iye han, K'a kọ ni lọna Ọlọrun, B'iwa Kristi lo ri. A gba ọrọ Rẹ gbọ, Busi igbagbọ wa; Ohun t'a se fun ẹni Rẹ, Jesu, a se fun Ọ.
8.
1. ỌRẸ ayé ki lo jamọ, Ohun asan ni mo mọ si, Ko si alanu bi Jesu, Alawo kọ, Ọlọrun ni, Adawunse kọ, Ọlọrun ni, Eniyan kọ, Ọlọrun ni. 2. O yẹ ki n fi Jesu s'ọrẹ, Ko si ọrẹ kan bi Jesu, Jesu to fẹ wa d'oju 'kumhh Babalawo kọ Ọlọrun ni, Awolẹ kọ, Ọlọrun ni, Eniyan kọ Ọlọrun ni. 5. 'Gbati mo joko n'ile mi, Esu wa d'ẹru b'ọkan mi, Sugbọn Jesu gbe mi leke, Wọn ni mo ku l'arayé sọ, Wọn l'o ti ku larayé sọ, Sugbọn Jesu da mi silẹ.

credits

released February 1, 2019

Orin Adura, or Songs of Prayer is a series of music projects that seeks to creatively preserve hymns in the Yoruba language.


Violin - Alicia Enstrom
Violin - Wanda Vick
Viola/Orchestration - Kristin Wilkinson
Cello - Paul Nelson

Acoustic Guitar - Pete Bordanali
Electric Guitar - Dug Grieves
Studio Engineer/Steel Guitar - Bob Angelo
Upright Bass: Kevin "Swine" Grantt
Organ - Dennis Wage
Studio Engineer - Andy Freeman


Penny Whistle, Flute, Soprano/Alto/Tenor/Baritone Sax: Sam Levine
Trumpet, Flugel Horn: Mike Haynes
Trombone/Bass Trombone : Josh Scalf

Drums: Evans Atta Fynn
Talking Drum, Omele & Percussion: Tosin Ajirotutu
Background Vocals: Eniola Solomon, Bunmi Oluwasesin, Bimbo Olarubofin, Olakunbi Solomon

Bass, Strings/Horns Arrangement: Femi “Femdouble” Ojetunde
Lead Vocals, Piano, Hymn Arrangement: Tolu Akande

Recorded & Mixed @ Angello Sound Studio (Nashville, TN)

Co-Producer: Tolu Akande
Producer: Femi “Femdouble” Ojetunde
Executive Producer: Dr. Tunde Badru

©Tolu Akande Music 2018

license

all rights reserved

tags

about

Tolu Akande Atlanta, Georgia

BOOKING:
470-326-0916

toluakandemusic@gmail.com

Christ-follower. Proudly Nigerian.

"Let me write the songs of a nation, I care not who writes its laws."

The reason why I do hymns? Because the 7 year-old and the 70 year-old alike will sing them. Additionally, they are sound doctrine and theology placed to anointed melodies that have stood the test of time!
... more

contact / help

Contact Tolu Akande

Streaming and
Download help

Shipping and returns

Redeem code

Report this album or account

If you like Tolu Akande, you may also like: