Get all 16 Tolu Akande releases available on Bandcamp and save 25%.
Includes unlimited streaming via the free Bandcamp app, plus high-quality downloads of Orin Adura, Volume 3, Orin Awe at'Adura (Medley Single), A Nsoro Ile Bukun Ni (Single), Olorun Agbaye (Single), Sa Gbekele (Single), Ma Toju Mi (Single), Orin Adura, Volume 2, Ọba Awọn Ẹni Mimọ (Single), and 8 more.
1. |
Mimọ, Mimọ, Mimọ
01:29
|
|||
MIMỌ, Mimọ, Mimọ Olodumare,
Ni kutukutu ni'wọ o gbọ orin wa,
Mimọ, Mimọ, Mimọ! Oniyọnu julọ,
Ologo mẹta lai Olubukun.
---
Holy, holy, holy
Lord, God Almighty
Early in the morning our song shall rise to Thee
Holy, holy, holy
Merciful and mighty
God in three persons blessed Trinity
|
||||
2. |
Ọba Awọn Ẹni Mimọ
05:14
|
|||
1. ỌBA awọn ẹni mimọ
T'o mọ 'ye awọn 'rawọ;
Ọpọ ẹni t'Ẹda gbagbe,
Wa yika itẹ Rẹ lai.
Egbe: Mimọ Mimọ (6 times)
Lo ye Ọ,
Iwọ l'a ba ma f'iyin fun,
Ọlọrun, Edumare.
2. Ẹni t'o wa ninu 'mọlẹ,
T'oju ẹnikan ko ri;
Mose ri akẹyinsi Rẹ,
Oju Mose ran b'orun.
3. Mole ti ‘kuku aiye bo
Ntan mole roro loke
Nwon je omo alade l'orun
Eda gbagbe won t‘aiye.
4. Lala at'iya wọn fun Ọ,
Ẹda ko royin rẹ mọ;
Iwa rere wọn farasin,
Oluwa nikan lo mọ.
Egbe: Mimọ Mimọ (6 times)
Lo ye Ọ,
Iwọ l'a ba ma f'iyin fun,
Ọlọrun, Edumare.
|
||||
3. |
Ibase P'Oluwa
05:24
|
|||
4. |
Jesu, Mo Wa S'ọdọ Rẹ
04:23
|
|||
5. |
Jesu Lorukọ to Ga Ju
04:18
|
|||
1. JESU lorukọ to ga ju,
Layé a ti lọrun;
Awọn Angẹli wolẹ fun,
Esu, bẹru o sa.
Egbe: Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,
Ipe miiran ko si,
O daju wi pé Jesu ku,
Ani f'emi ẹlẹsẹ.
3. Olugbala sẹgun iku,
Ijọba Satan fọ;
Gbogbo ẹda ẹ bu sayọ,
Ka yin Baba logo.
Egbe: Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,.....etc.
7. Jesu, fọ itẹgun esu,
Iwọ l'Ọba Ogo;
Iyin, ope ni fun Baba,
Ni fun Mẹtalọkan.
Egbe: Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,
Ipe miran ko si,
O daju wi pé Jesu ku,
Ani f' emi ẹlẹsẹ.
|
||||
6. |
Kérúbù Pẹlu Séráfù
04:21
|
|||
1. KÉRÚBÙ pẹlu Séráfù,
Ki yoo si nkan,
B'esu gbe tasi rẹ si wa,
Ki yoo si nkan,
Maikel Mimọ Balogun wa,
Y'o fọ 'tẹgun esu tutu,
Esu y'o wolẹ lẹsẹ wa,
Ko le si nkan.
2. Asiwaju ẹ ma bẹru
Ki yoo si nkan;
'Gbati Jesu wa pẹlu wa,
Ki yoo si nkan,
Sa gbadura, Asiwaju,
Oke nla yoo di pẹtẹlẹ,
Ayé ko le ri wa gbe se,
Ko le si nkan.
6. Ẹgbẹ Akọrin ẹ mura,
Ki yoo si nkan
Aluduru at'Afunpe,
Ki yoo si nkan;
Mura lati kọrin Mose,
K'ẹ yin Ọdaguntan logo,
K'a jumọ kọ Halleluyah,
Ko le si nkan.
8. Ogo ni fun Baba l'oke,
Ki yoo si nkan;
Ogo ni fun Ọmọ l'oke,
Ki yoo si nkan;
Ogo ni fun Ẹmi Mimọ ,
Ogo ni fun Mẹtalọkan,
Lagbara Olodumare,
Ko le si nkan.
|
||||
7. |
Ohun T'a Fi Fun Ọ
03:15
|
|||
OHUN t'a fi fun Ọ
Tirẹ ni Oluwa:
Gbogbo ohun ti a si ni,
Ọwọ Rẹ lo ti wa.
Jẹ k'a gba ẹbun Rẹ,
Bi iriju rere;
Bi O si ti mbukun wa to,
Bẹ l'a o fi fun Ọ.
K'a tu onde silẹ,
K'a f'ọna iye han,
K'a kọ ni lọna Ọlọrun,
B'iwa Kristi lo ri.
A gba ọrọ Rẹ gbọ,
Busi igbagbọ wa;
Ohun t'a se fun ẹni Rẹ,
Jesu, a se fun Ọ.
|
||||
8. |
Ọrẹ Ayé Ki Lo Jamọ
05:54
|
|||
1. ỌRẸ ayé ki lo jamọ,
Ohun asan ni mo mọ si,
Ko si alanu bi Jesu,
Alawo kọ, Ọlọrun ni,
Adawunse kọ, Ọlọrun ni,
Eniyan kọ, Ọlọrun ni.
2. O yẹ ki n fi Jesu s'ọrẹ,
Ko si ọrẹ kan bi Jesu,
Jesu to fẹ wa d'oju 'kumhh
Babalawo kọ Ọlọrun ni,
Awolẹ kọ, Ọlọrun ni,
Eniyan kọ Ọlọrun ni.
5. 'Gbati mo joko n'ile mi,
Esu wa d'ẹru b'ọkan mi,
Sugbọn Jesu gbe mi leke,
Wọn ni mo ku l'arayé sọ,
Wọn l'o ti ku larayé sọ,
Sugbọn Jesu da mi silẹ.
|
Tolu Akande Atlanta, Georgia
BOOKING:
470-326-0916
toluakandemusic@gmail.com
Christ-follower. Proudly Nigerian.
"Let me write the songs of a nation, I care not who writes its laws."
The reason why I do hymns? Because the 7 year-old and the 70 year-old alike will sing them. Additionally, they are sound doctrine and theology placed to anointed melodies that have stood the test of time!
... more
Streaming and Download help
If you like Tolu Akande, you may also like:
Bandcamp Daily your guide to the world of Bandcamp